Ẹ ra motor one fifty thousand, ẹnì k'oma taku lóru
Ẹ tí jonz (ẹ jonz)
Ẹ ti jonz (ẹ jonz)
Nini dé
(Ẹ jonz)
Ẹ gb'ọtí lẹ, kẹ jonz
Ẹnu o ẹnu, ọrọ ẹnu important
Ẹnu lẹ'nu temi, máfi bèrè òun tó dára
K'oma gbàgbé mí, Ẹlẹ'dàá mí
Irè pàdé mí
Jẹlosimi, lọ jókò (ẹ lọ jókò)
Ẹ kéré gan, ẹ tí pọ tó (ẹ tí pọ tó)
Bàbá Ìjẹ'bú fún mí l'eyọ kan
Fún mí ní number kín jẹ, kín tà tete eh
Àre tí bèrè, kẹ suure síbí
Ẹ t'ara ṣáṣá ké gbé soolu, kìí body yìn tele
Mójú kelele, b'òṣùpá bà yọ k'aṣeré alẹ (kúrò ńbẹ)
You really wanna turn the party down
Party don turn on a boggy-boogy down, go down, well done
I like the way you do
When there's life, there is hope
Believe in yourself, don't belittle yourself
(Wolo, wolo-wolo wolo-wolo)
(Gbéṣẹ́) gbéṣẹ́ sókè o (gbéṣẹ́)
Gbé body sókè o (gbéṣẹ́)
Ọmọ ológo gbéra tan (gbéṣẹ́)
Jí, másún (gbéṣẹ́)
Ẹnì ṣáṣẹ l'agbowó (gbéṣẹ́)
Ọlọhun o s'ọjoró (gbéṣẹ́)
Nkuyo, ọwọ mi dá o? (Gbéṣẹ́)
Ẹ máa jẹ ko japa o (gbéṣẹ́)
Gbéṣẹ́ sókè oh (gbéṣẹ́)
Gbé body sókè o (gbéṣẹ́)
(Kúrò ńbẹ) goat dey dance, aboki dey laugh
Goat no know say aboki wan use am for suya
Òyìnbó ní, "Life is vocabulary, methaphorlosis"
Life is concogariculous, ọrọ leṣín òwe
T'ẹmi bawa, ìrètí ń bẹ
Kola Olawuyi ní Nkan Ńbẹ
Nítorí ọbọ o j'ọ'gẹ'dẹ' mọ, ọwọ l'ejo ńjẹ'
Gbogbo slay mama, come and miliki to my music
It's very unique, nourish bí ti miliki
Kiki, do you love me?
Are you riding? Do you really want me?
T'Olubadan báwọ knicker burger, boolu ló fẹ lọ gbà (gbà-gbá-gbà)
T'oba rí NEPA to ń lo laptop, boya wire lo fín ja
(Gbéṣẹ́) gbéṣẹ́ sókè o (gbéṣẹ́)
Gbé body sókè o (gbéṣẹ́)
Ọmọ ológo gbéra tan (gbéṣẹ́)
Jí, másún (gbéṣẹ́)
Ẹnì ṣáṣẹ l'agbowó (gbéṣẹ́)
Ọlọrun o s'ọjoró (gbéṣẹ́)
Nkuyo, ọwọ mi dá o? (Gbéṣẹ́)
Ẹ máa jẹ ko japa o (gbéṣẹ́)
Àwọn ọmọ benefit (gbéṣẹ́)
Cotonou wọ Port Novo (gbéṣẹ́)
Gbé body sókè o
Àwọn slay mama tóń bà tí rí Snapchat
Wọn a t'ojú, t'ote
Wọn a demo' pẹ'lú flower lórí
Jẹlosimi, lọ jókò (ẹ lọ jókò)
Ẹ kéré gan ẹ tí pọ tó (ẹ tí pọ tó)
Bàbá Ìjẹ'bú fún mí l'eyọ kan
Fún mí ní number kín jẹ, kín tà tete eh
(Gbéṣẹ́) gbéṣẹ́ sókè oh (gbéṣẹ́)
Gbé body sókè oh (gbéṣẹ́)
Xsmile, bámí lu'lu (gbéṣẹ́)
Wọn tún tí jẹmi lówó (gbéṣẹ́)
IBD Dende (gbéṣẹ́)
Mo mọ Sir Kuti (gbéṣẹ́)
Mo mọ Femi Jaguar (gbéṣẹ́)
Lanre Typical (gbéṣẹ́)
Òrìṣà ní Baddy Ooṣha oh (gbéṣẹ́)
Arowolo ló ń ta motor oh (gbéṣẹ́)
Òun ta motor ni Texas (gbéṣẹ́)
K Sir, Sosse (gbéṣẹ́)
King of Marley (gbéṣẹ́)
Ọba Bombay (gbéṣẹ́)
Àkúré Oloyemekun (gbéṣẹ́)
Mo mọ Hot Water oh (gbéṣẹ́)
Èèyàn Iko Modina (gbéṣẹ́)
Aremọ Gucci (gbéṣẹ́)
Kehinde Fatai mi (gbéṣẹ́)
Tata, Emeka (gbéṣẹ́)
Niyass King Chievo (gbéṣẹ́)
Aláṣẹ Nikas, Teni level ní (gbéṣẹ́)
Ọmọ ọba Kumasi (gbéṣẹ́)
Lekan Agbainaki (gbéṣẹ́)
Mo mọ Billique (gbéṣẹ́)
Mo mọ Milli Hustle (gbéṣẹ́)
Otunba Cash (gbéṣẹ́)
Abu Abel (gbéṣẹ́)
Wọn à ni aji wọn lorin kọ (gbéṣẹ́)
Ìyẹn láṣe tún kọ (gbéṣẹ́)
Uh-uh, uh-uh-nh
Yeah, who's here?
Поcмотреть все песни артиста