This is Lanre Teriba (Atorise) Oro to wá ní le yí Oro to wá ní le yí Owo lọ ma solve ẹ Advice kò ooo E ma f'ejò pá mi No tension E yẹ ma pressure mi Wọn kín mú late comer nínú ká l'owo lowo No tension E ye ma pressure mi Wọn kín mú late comer nínú ká l'owo lowo, Mi ó kánjú waiye Mi ó ní konju lọ No long thing ashi ma bá wọn lowo K' anybody ye ma pressure mi T'oba nlowo ashi ma báwọn l'owo lowo Olódùmarè Olodumare wá mú inú mi dùn Àwọn tí mo fò'kan to o wọn'ba mi ninuje Olódùmarè Olodumare wá mú inú mi dùn Àwọn tí mo fò'kan to o wọn'ba mi ninuje As I no dey here for competition If you say you pass me no problem Me too I pass somebody B'opé b'oyá o ni ile aiye congratulation akárí gbogbo wa Olódùmarè Olódùmarè wá mú inú mi dùn Àwọn tí mo fò'kan to o wọn'ba mi ninuje No tension E ye ma pressure mi Wọn kín mú late comer nínú ká l'owo lowo No tension E ye ma pressure mi Wọn kín mú late comer nínú ká l'owo lowo Mi ó kánjú waiye Mi ó ní konju lọ No long thing ashi ma bá wọn lowo l'owo K'anybody ye ma pressure mi T'oba nlowo ashi ma báwọn lowo l'owo Olódùmarè Olódùmarè wá mú inú mi dùn Àwọn tí mo fò'kan to o wọn'ba mi ninuje Olódùmarè Olódùmarè wá mú inú mi dùn Àwọn tí mo fò'kan to o wọn'ba mi ninuje Iya mi ó lowo de bipe wa pin owo kan mi lojo kan Baba mi o ni ile de bipe wa pin ile kan mi t'obaya Iyen lo mu mi san sokoto ti mo fi gbogo igba hustle K'awon omo ti mo bi ma ba ji ya ti mo je Iyen to mu mi san sokoto ti mo fi gbogo igba hustle K'awon omo ti mo bi ma ba ji ya ti mo je No Tension ooo No tension E ye ma pressure mi Wọn kín mú late comer nínú ká l'owo lowo No tension E ye ma pressure mi Wọn kín mú late comer nínú ká l'owo lowo Mi ó kánjú waiye Mi ó ní konju lọ No long thing ashi ma bá wọn lowo Kí anybody ye ma pressure mi T'oba nlowo ashi ma báwọn l'owo lowo (E ye ma pressure mi) (E ye ma pressure mi) (Mo si ma lowo)