Kishore Kumar Hits

Toluwani - Ife Nla şarkı sözleri

Sanatçı: Toluwani

albüm: Ife Nla

Jesu ku fun araaye,(Jesu ku fun Araye)
Oku fun mi pelu o,(O ku fun mi pelu o)
Nipa ina re la mu mi larada,(nipa ina re la mumi larada)
INSTRUMENTAL
E wa wo iku oro e wa wo alaise, lori agbelebu
A mu bi odaran lalai se kan ri,A pa bi elese lalai jebi iku
Wonni e fun wa ni Banaba, Odaran ponbele
Won wa pa omo Olorun
Ife nla leyi o olorun ma je ki jebi
E wa wo iku oro e wa wo alaise,lori agbelebu
A mu bi odaran lalai se kan ri,A pa bi elese lalai jebi iku
Wonni e fun wa ni Banaba,odaran ponbele
Won wa pa omo olorun
Ife nla leyi o Olorun ma je ki jebi
Ewa wo omo olorun laarin elese,O n kigbe oro
Iya ti Enikan o le je,Lomo olorun fori ru
Nitori temi, (nitori tire) nitori tire (nitori tire)
Lati pa ise Esu run
Ife nla leyi o olorun ma je ki jebi
E wa wo iku oro e wa wo alaise,lori agbelebu
A mu bi odaran lalai se kan ri,A pa bi elese lalai jebi iku
Wonni e fun wa ni Banaba,Odaran ponbele
Won wa pa omo Olorun
Ife nla leyi o olorun ma je ki jebi
Agba n roju rorun o Wonni ko kara ile
Wonni ko kero ona Wonni akutuku re
Nitori temi Won faso mo lara
Won tun de lade egun ti ki ise ore ara
Iya wo omo re omo wo iya re o
Lara oro meje iyen ninu irora
E wa so fun mi na, se iwo le fi emi re lele?
Kaye wa fi Ibi sun fun o ife nla leyi o kolorun ma je ki jebi
Ah ife nla,ife nla,ife nla,ife nla!
Eje re lo so mi di Eniyan to pe
Ah ife nla,ife nla,ife nla,ife nla!
Ah!
Aanu se mi o ninu iwe johanu
Pilatu gbo tenu re,O ri wipe kojebi
Sebi aimo wawu kokan abinu Eni
Pilatu so fun won pe,alaise lefe pa
Wonni iyen ko kan wa,sa ti fun wa ni Banaba
Wonba kan Jesu mogi, oh!
What a friend we have in Jesus,togba iku awa ku
E wa wo iku oro e wa wo alaise,lori agbelebu
A mu bi odaran lalai se kan ri,A pa bi elese lalai jebi iku
Wonni e fun wa ni Banaba,Odaran ponbele
Won wa pa omo Olorun
Ife nla leyi o olorun ma je ki jebi
E gbo kilose na? ti won fi mu?
Sopa Eniyan ni? o sun mi
Eniyan buru won roro gan
Sugbon adupe,O jinde ojuti ota iyinrere
E gbo kilose na? ti won fi mu?
Sopa Eniyan ni? o sun mi
Eniyan buru won roro gan
Sugbon adupe,O jinde ojuti ota iyinrere
E wa wo iku oro e wa wo alaise, lori agbelebu
A mu bi odaran lalai se kan ri,A pa bi elese lalai jebi iku
Wonni e fun wa ni Banaba,Odaran ponbele
Won wa pa omo Olorun
Ife nla leyi o olorun ma je ki jebi

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar