Kishore Kumar Hits

Pastor J. A. Adelakun - Satani Kanjangbon şarkı sözleri

Sanatçı: Pastor J. A. Adelakun

albüm: Amona Tete Mabo Evergreen


Baba wa mbo o,
Jesu mbo, ko nipe de mo
Alagbara mbo, Jesu wa mbo wa
Jesu wa mbo lati wa se dajo aye.
Jesu mbo, ko nipe de mo
Jesu mbo, ko nipe de mo
Gbogbo oju ni yi o ri, at'awon to kan Jesu mo gi (oun mbo o)
Jesu mbo, ko nipe de mo
Alagbara mbo, Jesu wa mbo wa
Jesu wa mbo lati wa se dajo aye
Ti Jesu ba de
Satani yi o fere ge
Ti Jesu ba de
Satani yi o d'awati o
Satani kanjogbon, o kanjogbon o daran
T'ori Jesu wa mbo lati wa se dajo aye
Satani kanjogbon, kanjogbon o keran
Satani kanjogbon, kanjogbon o daran
T'ori Jesu wa mbo lati wa se dajo aye
Ojo ti pe o, to ti n dale aye ru
Ojo ti pe o, to ti n bale aye je
Ka f'omo olomo seso
Ise owo re ni (bee ni)
Ka d'eniyan n'igbekun
Ise owo re ni
Eni to fe se ife Jesu
Iwo lo de won lona o
O daju, satani a jiya
Ti Jesu ba de
Satani kanjogbon, o kanjogbon mo loru gi oyin
Tori Jesu wa mbo lati wa se dajo aye
Satani kanjogbon, kanjogbon o keran
Satani kanjogbon, kanjogbon o daran
Tori Jesu wa mbo lati wa se dajo aye
Gbogbo ayanfe o, e mura sile o
Eyin ayanfe o, e mura de Baba o
Eyin ayanfe, e jo e mura sile o
Gbogbo ayanfe o, e mura de Baba
Laipe ojo ta o mo o, Baba wa yi o yo, lawosanmo o
Bi o ti yo pelu awon ogun orun
T'on ko mimo mimo
Eyin ayanfe, tori na e mura sile o
Satani kanjogbon, kanjogbon ti Jesu ba de
Satani a jiya o, ti Jesu ba de
Tori Jesu wa mbo lati wa se dajo aye (o kanjogbon o)
Satani kanjogbon, kanjogbon o keran
Satani kanjogbon, kanjogbon o daran
Jesu wa mbo lati wa se dajo aye (O fere de o)
Satani kanjogbon, kanjogbon o keran
Satani kanjogbon, kanjogbon o daran
Jesu wa mbo lati wa se dajo aye
Satani kanjogbon, kanjogbon keran
Satani kanjogbon, kanjogbon o daran
Jesu wa mbo lati wa se dajo aye.
(End)

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar