Kishore Kumar Hits

Blessing - Hallelujah şarkı sözleri

Sanatçı: Blessing

albüm: Hallelujah


Intro
O joko sínú imọlẹ
Láàrin ọpọ irawọ
King of kings
Great I am
Mighty God, King of kings
Solo 1
O joko sinu imọlẹ
Láàrin irawọ
Ògo s'omo ọlọrun
Ògo sí mẹtalọkan (2ce)
Chorus
Hallelujah hallelujah
L'orin ti wọn nkọ
Hallelujah hallelujah
L'orin wọn lọrun
Hallelujah sí Bàbá
Hallelujah si Ọmọ
Hallelujah si Emi mimọ o
Ogo sí mẹtalọkan
O joko sínú imọlẹ
Láàrin ọpọ irawọ
Great I am
Prince of peace, wonderful
Glory to the King
Solo 2
He is seated in the heavenlies
He rules in all the Earth
Glory to King of Kings
Glory to the Lamb of God
He is seated in the heavenlies
He rules in all the Earth
Glory to King of Kings
Glory to the Lamb of God
Hallelujah hallelujah
L'orin ti wọn nkọ
Hallelujah hallelujah
L'orin wọn lọrun
Hallelujah sí Bàbá
Hallelujah si Ọmọ
Hallelujah si Emi mimọ o
Ogo sí mẹtalọkan
Hallelujah hallelujah
L'orin ti wọn nkọ
Hallelujah hallelujah
L'orin wọn lọrun
Hallelujah sí Bàbá
Hallelujah si Ọmọ
Hallelujah si Emi mimọ o
Ogo sí mẹtalọkan
Vamp
Hallelujah
Hallelujah si Bàbá
Hallelujah si Ọmọ
Hallelujah si Emi mimọ o
Ògo sí mẹtalọkan
Sing as much as you're led

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar