Kishore Kumar Hits

Angelique Kidjo - Alikama şarkı sözleri

Sanatçı: Angelique Kidjo

albüm: Queen of Sheba


Èmi Makeda, ti a toun ma m'kpè ni Balkis
Èmi ni Ayaba ti awọn guusu
Èmi Makeda, ti a toun ma m'kpè ni Balkis
Èmi ni Ayaba ti awọn guusu
O fi mi, o fi mi tché èlèwon ti è
O fi mi, o fi mi tché èlèwon ti è
Olọgbọn ti ọlọgbọn èyin Solomoni
Eyin l'Oba Jerusalemu
Èmi Makeda, ti a toun ma m'kpè ni Balkis
Èmi ni Ayaba ti awọn guusu
Èmi Makeda, ti a toun ma m'kpè ni Balkis
Èmi ni Ayaba ti awọn guusu
O fi mi, o fi mi tché èlèwon ti è
O fi mi, o fi mi tché èlèwon ti è
Olọgbọn ti ọlọgbọn èyin Solomoni
Eyin l'Oba Jerusalemu

Èmi Makeda, ti a toun ma m'kpè ni Balkis
Èmi ni Ayaba ti awọn guusu
Èmi Makeda, ti a toun ma m'kpè ni Balkis
Èmi ni Ayaba ti awọn guusu
Èmi mo fẹ lati lọ si ile mi
Èmi mo fẹ lati lọ si ile mi
Olọgbọn ti ọlọgbọn èyin Solomoni
Eyin l'Oba Jerusalemu
Ah Ah Ah
Ah Ah Ah
Ah Ah Aaaah
Bè enin awọn onidajọ,
Won dadjo mi l'Oòrùn
Emin ole lo ilé mi mon,
Bè enin awọn onidajọ,
Won dadjo mi l'Oòrùn
Emin ole lo ilé mi mon,
Ki ni won ma jin si lè ninu òkunkun
Shugbon o si wa l'ayé!
Igbami oma parun ninoun ofo
Lèè kan nan ni ayé man kpada wa
Ki ni won ma jin si lè ninu òkunkun
Shugbon o si wa l'ayé!
Igbami oma parun ninoun ofo
Lèè kan nan ni ayé man kpada wa
Ki ni won ma jin si lè ninu òkunkun
Shugbon o si wa l'ayé!
Igbami oma parun ninoun ofo
Lèè kan nan ni ayé man kpada wa

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar