Kishore Kumar Hits

Angelique Kidjo - Ahan şarkı sözleri

Sanatçı: Angelique Kidjo

albüm: Queen of Sheba


Kossi, kpashan kan
Kossi Shèkèshèkè kan
Kossi igban kan
Kossi Shèkèshèkè kan
Kossi, kpashan kan
E sọ fun mi Solomoni, ohun gbogbo lo gbé wa lọtọ nin sin
E sọ fun mi Solomoni, ohun gbogbo lo gbé wa lọtọ nin sin
Eyin nin Ọba, enin Oba Jérusalem
Alagbara ọkunrin, ọkunrin funfun
Ni waju yin, Emi ni obinrin dudu ti è kpatchè foun
E sọ fun mi Solomoni, ohun gbogbo lo gbé wa lọtọ nin sin
E sọ fun mi Solomoni, ohun gbogbo lo gbé wa lọtọ nin sin
Alagbara ọkunrin, ọkunrin funfun
Eyin ti èsso m'kpé moji omi orisun yin
Alagbara ọkunrin, ọkunrin funfun
Shugbon m'bo ni agbara yin kouro?
Ninou owo wo lè n'mou ida yin o?
Shugbon M'bo l'owa lara yin oooo
Shugbon m'bo ni agbara yin kouro?
Kabi èssè yin to n'sare lo si ogun
Shugbon te ni ailopin Agbara léri eniyan

E sọ fun mi Solomoni, ohun gbogbo lo gbé wa lọtọ nin sin
E sọ fun mi Solomoni, ohun gbogbo lo gbé wa lọtọ nin sin
Eyin nin Ọba, enin Oba Jerusalemu
Alagbara ọkunrin, ọkunrin funfun
Ni waju yin, Emi ni obinrin dudu ti è kpatchè foun
E sọ fun mi Solomoni, ohun gbogbo lo gbé wa lọtọ nin sin
E sọ fun mi Solomoni, ohun gbogbo lo gbé wa lọtọ nin sin
Alagbara ọkunrin, ọkunrin funfun
Emi ti èsso m'kpé moji omi orisun yin
Alagbara ọkunrin, ọkunrin funfun
Shugbon m'bo ni agbara yin kouro?
Ninou owo wo lè n'mou ida yin o?
Shugbon M'bo l'owa lara yin oooo
Shugbon m'bo ni agbara yin kouro?
Kabi èssè yin to n'sare lo si ogun
Shugbon te ni ailopin Agbara léri eniyan

Kossi, kpashan kan
Kossi Shèkèshèkè kan
Kossi igban kan
Kossi Shèkèshèkè kan
Kossi, kpashan kan
Kossi Shèkèshèkè kan
Kossi igban kan
Kossi Shèkèshèkè kan

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar