Kishore Kumar Hits

Sola Allyson - Adun şarkı sözleri

Sanatçı: Sola Allyson

albüm: Adun


Iran oju ti mo ri re oo
Ifihan ti mogba to yo simi ni yi ooo
Adun a po fun mi, ona a ma la daada
Mori adun mo ladun, were ladun wole de
Eyi mo bere ni mori, oluda mi sope
Edumare fadun s'ola mi, modupe adun ni 2xe.
Mo gb'adun de ooo, e tewo, e wa gba.
Eni ba fe koteti, oludani lo gbese to po gan ran mi wa
Boju woke ko r'adun, emi boju woke mo r'adun.
Ilakaka o sa simbe, orun logbadun yen wa.
Iran oju ti mo ri re oo
Ifihan ti mogba to yo simi ni yi ooo
Adun a po fun mi, ona a ma la daada
Bee ni
Mori adun mo ladun, were ladun wole de
Eyi mo bere ni mori, oluda mi sope
Edumare fadun s'ola mi, modupe adun ni 2xe.

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar