Akosile ti duro akosile o le tase oun toluwa base eda kan kole yi Pada ibi ori n gbe ni lo kese ma si ni lona oun to wun eleduwa lo le Yan fun wa atibi atire ton sele lala eda kole ye e e akosile ti duro Kole tase o o o, ayanmo eda ti duro kirakita o dola laye gbogbo eto Olorun kose ni tole ba tun to gbogbowa lan sare kiri pe ka lola ka Jeniyan sugbon ta lole mo ibi ori dawun si atibi atire ton sele lala Eda kole ye e e akosile ti duro kole tase o o o wa ba mi se, Wa ba mi se o baba koma se le mo mi kaye Mi ma koro bi ewuro ara ire ni kofimi da. ♪ Kadara eda ti duro ife eleda o le ye lai ona ti o ba wun olorun oun Lole mu ese eda to ori e o dade ofe jo ba o wa n ba yanmo jijakadi Boti wun e ni to dale lose n foyin si atibi atire ton sele lala eda ♪ Kole ye e e akosile ti duro kole tase o o o, Eniyan ma yo ra leun koya gba folorun lo to womo meji tabi lojo kan Ayanmo ototo loyan onise ika n sorire onise re wan to si Awa bi Olorun lere bo se je boti wun oluwa lon soro kose ni tole da lejo Akosile ti duro kole tase o o o wa ba mi se wa ba mi se o baba Koma se le mo mi kaye mi ma koro bi ewuro ara ire ni kofimi da. ♪ Oro olorun ede ni ileri re ko le ye lai oun ti oluwa ba pinu ife ota Kan o le pada oti pinu pe ki sorire pe ki lola ki n jeniyan oun Toluwa ba ko ko seni to le yi bo ti wun oluwa lon soro oun lo layo Ati ola akosile ti duro kole tase o o o wa ba mi se wa ba mi se, Wa ba mi se o baba koma se le mo mi kaye mi ma koro bi ewuro ara ire ♪ Ni kofimi da, wa ba mi se mo bebe, Iwo lo ran mi wa ba mi se kaye mi Ma koro bi ewuro ara ire ni kofimi da.