Duro timi o, Ololufe Ife ti ko labuku ni ko ba mi lo Duro timi o, Ololufe Ife ti ko labawon ni ko ba mi lo Ife bi Eji Owuro, Latagbala Eledumare lo ti se wa Ife to tooro minimini, Tabawon aye kan o le ba je o Ololufe feran mi laisetan Ife bi Eji Owuro, Latagbala Eledumare lo ti se wa Ife to tooro minimini, Tabawon aye kan o le ba je o Ololufe feran mi laisetan Femi bi oju ti n f'emu Femi bi irun ti n f'ori Femi bi eyin ti n f'enu Femi teerin teerin Femi taayo taayo Femi taara taara Ololufe feran mi laisetan Femi bi oju ti n f'emu Femi bi irun ti n f'ori Femi bi eyin ti n f'enu Femi teerin teerin Femi taayo taayo Femi taara taara Ife bi Eji Owuro, Latagbala Eledumare lo ti se wa ♪ Ife to tooro minimini, Tabawon aye kan o le ba je o Ololufe feran mi laisetan ♪ Ba mi s'ootito, Mo fe o tooto Ba mi s'ododo, Mo fe o pelu ododo Ba mi s'ootito, (Ololufe) Mo fe o tooto Ba mi s'ododo, Mo fe o pelu ododo B'ogiri o ba la'nu, Alangba o le w'ogiri B'ogiri o ba la'nu, Alangba o le w'ogiri Eleda lo yan wa papo, Esu ko ni yawa o Ife bi Eji Owuro, Latagbala Eledumare lo ti se wa Ife to tooro minimini, Tabawon aye kan o le ba je o Ololufe feran mi laisetan. A ma lowo lowo A ma kole mole A ma bimo lemo A ma sayo mayo A ma shola mola Ka sa mufe Eledumare se, laisetan.
A ma lowo lowo A ma kole mole A ma bimo lemo A ma sayo mayo A ma shola mola Ka sa mufe Eledumare se, laisetan. Ife bi Eji Owuro, Latagbala Eledumare lo ti se wa Ife to tooro minimini, Tabawon aye kan o le ba je o Ololufe feran mi laisetan. ♪ Gb'amoran mi, Ololufemi! Oluranlowo la fi mi se fun o lat'orun wa F'eti s'amoran mi, Ololufemi! Oluranlowo la fi mi se fun o lat'orun wa Kaj'orin ka s'ogo, l'oruko Olorun Alabinrin la fi mi se fun o lat'orun wa M'okan ku ro ni asan aye Etan o da n kankan fun ni Ife at'ope lo le mu wa l'aye ja lai labawon M'okan ku ro ni asan aye Etan o da n kankan fun ni Ife at'ope lo le mu wa l'aye ja lai labawon Ife bi Eji Owuro, Latagbala Eledumare lo ti se wa Ife to tooro minimini, Tabawon aye kan o le ba je o Ololufe feran mi laisetan. ♪ Duro timi o, Ololufe Ife ti ko labuku ni ko ba mi lo ♪ Duro timi o, Ololufe Ife ti ko labawon ni ko ba mi lo
Duro timi o, Ololufe Ife ti ko leetan rara ni ko ba mi lo...