Ògo ìyìn ọlá Lóye Ọlọ́run Ọlọ́run àwọn ọmọ Ógùn Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún Ògo Ìyìn ọlá Lóye Ọlọ́run Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún Ọba tó f'amo mo wá Ọba tó lẹ' mi wá Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun Ọba t'ó f'amo mo wá Ọba t'ó lẹ' mi wá o Ọlọ'run àwọn ọmọ ogún Ọlọ'run àwọn ọmọ ogún Níbi tó lẹ'wá julo ni Ìwọ gbé Lórí obiiri ayé níwọ̀ wá o Imọ'lẹ' láṣọ re Ọlá lo fi ṣá'so bora Níbi tó lẹ' wá julo ni ìwọ gbé Lórí obiiri ayé ni'wo wá o Imọ'lẹ' láṣọ rẹ O ó Ọlá lo fi ṣá sọ bora Mo padà wá bí orísun ìfẹ' àkókò Mo ṣe itẹ fún ọ lógún ọkàn mi o Ọba tó lẹ' mi mi Ọba tó ní gbà mi Mo padà wá bí orísun ìfẹ' akoko Mo ṣe tẹ fún ọ lógún ọkàn mi o Ọba tó lẹ' mi mi Ọba tó ní gbà mi Ahhhhh Ahhhhh Ìwọ lọ lèmi mi ò Ìwọ lo nígbà mi Ìṣẹ'lẹ' inú ìṣẹ̀dá nṣá'fihàn àgbàrá rẹ Àwọn ohùn tàri n ṣáfihan ìṣe rẹ o Pẹ'lú ifilelẹ' tí ó lè Páráda láì láì Àrà ọwọ Rẹ ni gbogbo wọ́n Ṣe bí èyí tà ri là ń wi Àwọn ohùn tá a ò lè rí má bùsan yeye Àìmọye làwọn tá kan n mo l'àrà Ẹ'dá ó lè ṣá kàwé wọn Ibí tó lẹ'wá julo ni ìwọ gbé órí obiiri ayé ni'wo wá o Imọ'lẹ' láṣọ rẹ O ó Ọlá lo fi ṣá sọ bora Mo padà wá bí orísun ìfẹ' àkókò Mo ṣe itẹ fún ọ lógún ọkàn mi Ọba tó lẹ' mi mi Ọba tó ní gbà mi Mo padà wá bí orísun ìfẹ' akoko Mo ṣe tẹ fún ọ lógún ọkàn mi ò eh Ọba tó lẹ'mi mi Ọba tó ní gbà mi Ògo ìyìn ọlá Lóye Ọlọ́run Ọlọ́run àwọn ọmọ Ógùn Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún Ògo Ìyìn ọlá Lóye Ọlọ́run Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún Call: Ọba tó fún mí lé mi ọba tó lémi mi ẹni tó lé mi gàn gàn Resp: Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún Call: Ogo rẹ pọ púpò ṣe bí èyí tà le fara gbà mú là ń jẹ anfani ẹ Resp: Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun Call: Àìmọye àwọn èyí tá' ó lé mọ' bíi kò ṣé gbà ta ba sunmọ ibùgbé rẹ Resp: Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún Call: Ìyanu rẹ kọjá a fẹnu sọ ìwọ'n bá ti ọgbọ'n orí lè gbé là ń ṣá pé júwe fún Resp: Ọlọ'run àwọn ọmọ ogún Call: Olúwa àwọn ọmọ ogún kọjá àpèjúwe kò ṣe ní tó lè mọ ṣe rẹ Resp: Ọlọ'run àwọn ọmọ ogún Call: ẹni n bẹ lórí ìtẹ' á sì wà síbè sì bí ó ti wà láì láì ni yẹn ìyípadà kànkan ó sì Resp: Ọlọ'run àwọn ọmọ ogun Call: Gbogbo ògo gbogbo ọlá gbogbo agbara gbogbo ìjọba tìrẹ ṣá ní Reap: Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún