Mo ma ri ore Mo ma ri ore to po Oro ti o niye Mo ma ri ore Mo ma ri ore to po Oro ti o niye Amin o ase! Amin o ase! Amin oo Sebi awa ri Baba gb'ojule (Sebi awa ri Baba gb'ojule) Sebi awa ri Baba gb'ojule (Sebi awa ri Baba gb'ojule) Sebi awa ri Baba f'eyinti (Baba f'eyinti) Bee na laa ri Bee naa a se Sebi awa ri Baba gb'ojule Sometime ago, living in the darkness Ireti d'opin o Ko ma s'enikan a sa ba o Ife ti o lakawe (ko lakawe) o, lo wa mi ri (lo wa mi ri) O tan imole s'ona mi O gbe mi s'ejika wa'le Iyanu yen si wa O si ma a wa Tori awa ri Baba gb'ojule Sebi awa ri Baba gb'ojule, o daju saka (Sebi awa ri Baba gb'ojule) Sebi awa ri Baba gb'ojule (Sebi awa ri Baba gb'ojule) Sebi awa ri Baba f'eyinti (Baba f'eyinti) Bee naa la ri Bee naa a se Sebi awa ri Baba gb'ojule But right now My path is bright gan ni (O bright gaan) Ife to se yen wa sibe, ko le yi pada laye o Emi yo layo ninu Re, Alasepe oore O le se ju bee lo o, Olododo ni Baba Olutoju mi si wa, yo si ma a be Emi ma ri Baba gb'ojule Sebi awa ri Baba gb'ojule, dajudaju (Sebi awa ri Baba gb'ojule) Awa ma ri Baba gb'ojule o, ki i d'oju tini o (Sebi awa ri Baba gb'ojule) (Sebi awa ri Baba gb'ojule) Olubukun, Olufunni, lawa f'eyinti Bee naa la ri Bee naa a se Sebi awa ri Baba gb'ojule Bi eru wa, sibe o wa, ko le yi pada lailai Sebi awa ri Baba gb'ojule Alaanu, Olupese, Oludande, Oloore ni Sebi awa ri Baba gb'ojule Mo ri oore, oro to po, ileri Re a se mo mi lara Sebi awa ri Baba gb'ojule Mo gbeke le, mo mo A a se e, O ti so bee, oro Re ki i ye, ohun ni Baba Sebi awa ri Baba gb'ojule