Tani mo gbekele ti mo fi nsayo? Tani mo gbekele ti mo fi ngbese mo ngbe? Tani mo gbekele ti mo fi nyan? Tani mo gbekele ti mo fi nsayo? (Tani, tani gan?) Tani mo gbekele ti mo fi ngbese mo ngbe? Tani mo gbekele ti mo fi nyan? Igba eru ba mi sibe mo nsayo (mo nsayo) Igba eri ba mi sibe mo ngbese mo ngbe Igba eru bami sibe mo nyan Igbagbo, ireti lo mu mi nsayo (ayo ninu Baba mi) Igbagbo ireti lo mu mi ngbese mo ngbe Igbagbo ireti lo mu mi nyan Tani mo gbekele ti mo fi nsayo? Baba ni mo gbekele ti mo fi ngbese mo ngbe Oun mo gbekele ti mo fi nyan Igba eru ba mi sibe mo nsayo (nitori mo je omo Baba) Igba eri ba mi sibe mo ngbese mo ngbe Igba eru bami sibe mo nyan Igbagbo ireti lo mu mi nsayo Igbagbo ireti lo mu mi ngbese mo ngbe Igbagbo ireti lo mu mi nyan Ninu igbekele, anu ti ki isa, iyen lo mu mi debi o owa titi lae Anu to ba to si wa ko le gbon mi re Bi mi o ba ti joo re o wa titi lae O wa titi lai o O wa titi lai o O wa titi lai, o wa titi lai Anu to ba to si wa ko le yin mi nu, lai-lai Bi mi o ba ti joo re o wa titi lae Ore ofe kin ma lo joo re ni mo nwa si Ileri to se ta si mo se kole ju mi le Anu to mu mi debi si wa, kole tan lai-lai o Bi mi o ba ti joo re, o wa titi lae O wa titi lai o O wa titi lai O wa kole tan o O wa titi lai Anu to ba to si wa ko le gbon mi re lai-lai Bi mi o ba ti joo re o wa titi lai Itooona ni mo gba Itona ni mo gba kinle ma sayo Itona ni mo bebe fun o Iranwo ni mo fe lati ma rina yi Imole a ma tan bi mo ti nlo (Itona la toke wa), Itona ni mo gba kinle ma sayo Iranwo ni mo fe lati ma rina yi Imole a ma tan bi mo ti nlo Itona ni mo gba kinle ma sayo (igbekele mi wa niun Baba, oju ole ti mi lai-lai) Iranwo ni mo fe lati ma rina yi Imole a ma tan bi mo ti nlo Imole ko ma tan bi mo ti nlo (Iwaju, iwaju lopa ebiti mi a ma resi) Imole ko ma tan bi mo ti nlo Imole ko ma tan bi mo ti nlo