Kishore Kumar Hits

Sola Allyson - Taní́ - Live şarkı sözleri

Sanatçı: Sola Allyson

albüm: ÌRÌ (The Album Live)


Tani mo gbekele ti mo fi nsayo?
Tani mo gbekele ti mo fi ngbese mo ngbe?
Tani mo gbekele ti mo fi nyan?
Tani mo gbekele ti mo fi nsayo? (Tani, tani gan?)
Tani mo gbekele ti mo fi ngbese mo ngbe?
Tani mo gbekele ti mo fi nyan?
(Igba eru ba mi)
Igba eru ba mi sibe mo nsayo (mo nsayo)
Igba eri ba mi sibe mo ngbese mo ngbe
Igba eru bami sibe mo nyan
Igbagbo, ireti lo mu mi nsayo (ayo ninu Baba mi)
Igbagbo ireti lo mu mi ngbese mo ngbe
Igbagbo ireti lo mu mi nyan
Tani mo gbekele ti mo fi nsayo?
Baba ni mo gbekele ti mo fi ngbese mo ngbe
Oun mo gbekele ti mo fi nyan
(Igba eru ba mi)
Igba eru ba mi sibe mo nsayo (ayo ninu baba mi)
Igba eri ba mi sibe mo ngbese mo ngbe (mo ngbese mo gbe)
Igba eru bami sibe mo nyan
(Igbagbo, ireti)
Igbagbo ireti lo mu mi nsayo
(Eni gbekele l'olowa koni jogun ofo)
Igbagbo ireti lo mu mi ngbese mo ngbe
Igbagbo ireti lo mu mi nyan
Ninu igbekele, anu ti ki isa, iyen lo mu mi debi o owa titi lae
Anu to ba to si wa ko le gbon mi re
Bi mi o ba ti joo re o wa titi lae
O wa titi lai o
O wa titi lai o
O wa titi lai
O wa titi lai
Anu to ba to si wa ko le yin mi nu
Bi mi o ba ti joo re o wa titi lae
Ore ofe kin ma lo joo re ni mo nwa si
Ileri to se ta si mo se kole ju mi le
Anu to mu mi debi si wa, kole tan lai-lai o
Bi mi o ba ti joo re, o wa titi lae
O wa titi lai o
O wa titi lai
O wa kole tan o
O wa titi lai
Anu to ba to si wa ko le yin mi nu lai-lai
Bi mi o ba ti joo re o wa titi lai
(Itooona ni mo gba)
Itona ni mo gba kinle ma sayo
(Iranwo ni mo fe)
Iranwo ni mo fe lati ma rina yi
Imole a ma tan bi mo ti nlo
(Itona la toke wa), Itona ni mo gba kinle ma sayo
Iranwo ni mo fe lati ma rina yi
Imole a ma tan bi mo ti nlo
(Imole ko ma tan bi mo ti nlo)
Imole ko ma tan bi mo ti nlo
(Iwaju, iwaju lopa ebiti mi a ma resi) Imole ko ma tan bi mo ti nlo
Imole ko ma tan bi mo ti nlo

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar