Kishore Kumar Hits

Sola Allyson - Ijoba A Re De şarkı sözleri

Sanatçı: Sola Allyson

albüm: Isodotun


Ijoba Re de, ase Re bere
Agbara wa, o ba sori mi
Ijoba Re de, ase Re bere
Agbara wa, o ba sori mi
Ijoba Re de, ase Re bere
Agbara wa, o ba sori mi
Ijoba Re de, ase Re bere
Agbara wa, o ba sori mi
Ijoba Re de, ase Re bere
Agbara wa, o ba sori mi
Ijoba Re de, ase Re bere
Agbara wa, o ba sori mi
Ijoba Re de, ase Re bere
Agbara wa, o ba sori mi
Okunkun ka, Imole de
Iranwo de, gbogbo ise n kun mi lowo
Ise mo wa se, ise Imole, ma a s' aseye
Ma a rin arinto, ma a rin arinye
Agbara wa, o ba sori mi
Okunkun ka, Imole de
Iranwo de, gbogbo ise n kun mi lowo
Okunkun ka, Imole de
Iranwo de, gbogbo ise n kun mi lowo
Ise mo wa se, ise Imole, ma a s' aseye
Ma a rin arinto, ma a rin arinye
Agbara wa, o ba sori mi
Mo f'ebun sola o
Bee naa lo ri
Mo f'ebun mi fogo fun Oluwa t'O l'ebun mi
Bee naa lo ri
Ijoba Re de o
Owo yida lori iseda mi
Ase Re lat' orun bere, bee naa lo ri
Owo yida lori iseda mi
Isodotun de ba mi ni 'rin ajo mi
Bee naa lo ri
My men shall not be few, iranwo lat' origun mereerin agbaye temi ni
Bee naa lo ri
Awon t'o ma gbe mi, t' 'on ma sugba ohun mo gbe ka 'ri, won wa s'ona mi
Bee naa lo ri
Ijoba Re de o
Owo yida lori iseda mi
Si ti aanu, si ti iranwo, si ti iserere, bee naa ni
Owo yida lori iseda mi
Iranwo ti mi o ri ri, ma a ri lona gbogbo, bee naa ni
Bee naa lo ri
Aye mi a bu ola fun O, Eni ti O ni ebun mi, bee naa ni
Bee naa lo ri
Bee naa lo ri o, pelu ase Baba mi
Owo yida lori iseda mi
Mo ti di omo
Apeere omo wa lara mi
Owo yida lori iseda mi
Agbara wa, O ba s'ori mi

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar