Kishore Kumar Hits

Gbenga Akinfenwa - Aanu Ni Mori Gba (Live) şarkı sözleri

Sanatçı: Gbenga Akinfenwa

albüm: Aanu Ni Mori Gba (Live)


Ki ma ma ise tori mo dara, tabi tori mo mo aduraa gba
Anu.Anu.Anu Ni mori gba e
Ki ma ma ise ile ti mo wa, tabi tori gbogbo iwe ti mo ka
Ki ma ma ise tori moni baba Isale, lo mu kokan mi fi bale.
Bi mo ba se njade nile
Aanu!
Call: Bi mo se nkore dele
Aanu!
Call: Mo nsori ire sere
Aanu... ko ma tele mi o

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar