Kishore Kumar Hits

LC Beatz - G.A.G.A (God and God Alone Yorubar Cypher) [feat. Oba Reengy, Daddy Verse, el Noel & Sola Shittu] şarkı sözleri

Sanatçı: LC Beatz

albüm: G.A.G.A (GOD and GOD Alone)


Ahhh
(Hook)
God And God Alone lo n je ti GAGA
O mu mi jade kuro ni para
Ko ma se lo miran mo to dara
Lo je kin ma pariwo, say me I'm going
GAGA(gagaga)
Me I'm going GAGA(gagagagagaga)
Me I'm going, me I'm going
GAGA(gagagagaga)
Ni bo ni motife
Bere si ni ṣàlàyé, farabale ko tẹ ti gbọ mi alaye eleyi gidi gan
Mi o wa be like e ṣeré at all o
I'm talking my father, yeah
Wọ ni kilode to ṣé ma n ka mi lara to ba ti d ọ'rọ' Jésù gan
Mo ma n sọ fun wọn, òun lo renew mi, mi o sọ'rọ' starch kan kan
Ama kip blowing the horn
O gbudọ yé wọn ni, bi ti tadiyẹ
Mo de ti sọ wípé, mi o ni gbenu dake till every of my padi hears
So I gat to press on even ti n ba rina lo iron,
My God is able, lo save me from the den lọ'jọ' kini àná
Devil no fit direct me
Ko ki n ṣé Tunde Kelani
The dude is under my feet, a fi bii ti shoe filami
Ọlọhun, o ti gbé mi lékè, mo fo lókè like I am le'kele'ke, lọ bi Leke
Òun ni GAGA, Òun ni first and the last
Ama tell everywhere, moo ni ṣéẹ'kẹ'
(HOOK)
Emi mimọ la wa mọ, omo a o fẹ mo yan
But I'll hold it down for my street, mo ṣi leniyan
Wo lọ n binu for their kinape, wọ n faraki
Jésù mi lo ran mi wa
Àwọn ni mo ba wa bi
Lege o Dotun lege o
Lori mic yi, I'm a heavy weight
Jegede o
Wọn o lé gbé mi o
Ee ri ran wo le ni o
Moral presence la wa n gbé kiri, a tun gbé wọlé o
Justice for the beatz
Oba Reegy ma na Barrister
Egbon MC, oni la ti sọ'rọ', mo ma ba wi Sir
GAGA ni mo gbé so ri
Mii gbejo, orí medusa
But we travel on the snakes kọja lo ri medusa
(Gagagagagagagaga) gbaso ké
Me I'm going
(Gagagagagagaga)
Awa lo mo F-A-D-A(fada)
Oti gbé wa sókè L-A-D-A(lada)
Therefore, awa ko le P-A-D-A(pada)
Ìgbàgbọ' mi duro lori G-A(ga)
Mo ti gbekelele G-A(ga)
Oya fada lada pada gaga
Sharp as alapata dagger
Jah Jehovah Rapha
El Elyon
El Shaddai
El Akrrmm
Mo ka n lẹ, mée ko bàtà
Pako ẹ'mí, ko saye butter
Mo fọlọhun belohun, maa je normal,
That's my prayer, simply because
Mi o ki n ṣé bastard
I no be BAAAASTARD
My papa na thunder
Papa na fire
So ti mi o ba lé ṣé signs and wonders
Fédéfọ' without rehearsal
Ṣé lo yẹ kẹ wa mi wale, tu mi láṣọ, ti mi si ta, fọ mi létí
(GA... you think I'm joking uhn... GA)
(Me I'm going, me I'm going GAGA)
(Me I'm going GAGA)
To ba ti gbọ GAGA, ko dee n ṣé bii ti white lady yen
Think about my father ti won o lé ba, ti o de ré bikan
E àwọn kan wa fẹ ma diṣi father mi
But anyway, mo gbé sori bi eni ti o ye lawa ni
Àwọn kan ni kolewerk, ẹ sọ fun wọn kan dá padà
Tori GAGA gan ni movement and the mode is on okada
Ìtùmò ẹ ni pé, a o ma lé pada seyin
If u hatin on us, Oyo lo wa bi e ni n gbé ni Iseyin, you know
I know say u bean cake bi eni n tákárà
Ogbeni, ti o ba ni Jésù, ṣé lo taraka
Keep it logged, bi iru Jamo to kọ raga
Ogbeni ko ni túmọ', to ba ti lè sé fun GAGA woos
(HOOK)
Ọlọ́run ni kan ni kan ṣoṣo
Ẹ'jẹ' ọ'dọ' àgùntàn, my logo
Iresi mi o dawa, na the word be my dodo
Sùúrù mi ti lérè
Ọlọ́run ti ṣògo
E ma bi mi lérè bi oro yen ṣé ma n dogo(dogo)
Yaro yaro, ibanuje paro
E ni to ba fẹ'ràn Jésù, oya jẹ a kolabo
E mi ti kọ Jé lori key C
Lojojumo ni mo n fi se nu gan ni bibi
Mo ti n di blessing, mo ti n di blessing
Gba bẹ yẹn, no more relenting
No more relenting, gba bẹ yen
Mi o ni sun seyin, mi o ni sun seyin
Gba bẹ yen
Mo ti n gba mi layé, ni mo n lu titititi kẹti
GAGA!!
GA
GA
GA

Поcмотреть все песни артиста

Sanatçının diğer albümleri

Benzer Sanatçılar